Kent Edunjobi Songs
EBENEZERI BY KENT EDUNJOBI, APEX CHOIR FT. EMMA OMG_MP3, VIDEO AND LYRICS
Anointed Gospel Singer Kent Edunjobi, has come up with a masterpiece tagged “Ebenezeri” featuring Emma OMG. The song is captivating and mind-blowing. The sound is amazing.
A beautiful expression of the thanksgiving.
DOWNLOAD EBENEZERI MP3 BY KENT EDUNJOBI X APEX CHOIR FT. EMMA OMG
Subscribe For More Updates! |
EBENEZERI BY KENT EDUNJOBI X APEX CHOIR FT. EMMA OMG OFFICIAL VIDEO
EBENEZERI LYRICS BY KENT EDUNJOBI AND APEX CHOIR FT. EMMA OMG
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti e ran wa lowo de
Ka’ma jo o kayo ka fogo folu
Ninu irinkerido mi laye, eh
Íwó lo bà mi sé
Àlubàríkà lówà mí rí
Èmi kó, isé ólórun ní
Èwu gbógbó ti mo là kójà
Ki mà isé àgbàràmi
Àtinudà ti mo di, lo njé ki dupé ore
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti e ran wa lowo de
Ka’ma jo o kayo ka fogo folu
Ebenezeri wa re oo
Ema ma se ese
Kima nse nipa agbara
Oluwa loni imo ati oye
Ogo ti àyé rí ti wón pologo
Iré lo bà wà se
Orin halleluya, hossana lo gbénu wa kó
Ése ibi ti èti béré
Esé ibi tí ébà dé
Adupé oluwàà
Ibi ti emu wa looo
Ibasepe oluwaaaa
Koti wa niti wa ooo
Nibo la ba jasi ooo
Amo ni sé yin, àdupé àtun ope da
Tori wipe
Awo kan gbele kéke
Awon kan gbekele éshin
Awa ta gbekele ooo
Ibi tomu wa de, ibi ogo ni
Lase wi pe
Orin halleluya
Orin hosana ooo
Orin ebenezer
Hosana lo gbenu wa kan
Ekorin ebenezeri
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti e ran wa lowo de
Ka’ma jo o kayo ka fogo folu
Ese ibi te ti beere
Ebenezeri wa re oo
Ema ma se ese
Kima nse nipa agbara
Oluwa loni imo ati oye
Ogo ti àyé rí ti wón pologo
Iré lo bà wà se
Orin halleluya, hossana lo gbénu wa kó
Oh oh oh oh
Ka pànu po Kàdupe
Ooooooooo
Kà korin ayo kà mó pé wà
Oh oh oh oh
Ka pànu po àdupe
Ooooooooo
Kà korin ayo kà mó pé wà
Tori pe
Agbón ígbé ibunkun àidiyé lé
To fi fun wa a a a
La nsé ndupe
Oh oh oh oh
Ka pànu po Kàdupe
Ooooooooo
Kà korin ayo kà mó pé wà
Oh oh oh oh
Ka pànu po Kàdupe
Ooooooooo
Kà korin ayo kà mó pé wà
Agbón ígbé ibunkun àidiyé lé
To fi fun wa a a a
La nsé ndupe
Moni
Agbón ígbé ibunkun àidiyé lé
To fi fun wa a a a
La nsé ndupe
Gbo gbo àye mí sóró ogo re
Tori abubu tàn oré
To se fun mi
Oh oh ah eh
La se ndupé
Ebenezeri wa re oo
Nibi ti e ran wa lowo de
Ka’ma jo o kayo ka fogo folu
Ebenezeri wa re oo
Ema ma se ese
Kima nse nipa agbara
Oluwa loni imo ati oye
Ogo ti àyé rí ti wón pologo
Iré lo bà wà se
Orin halleluya, hossana lo gbénu wa kan
Follow Scrolls Gospel on all social media platforms Call/WhatsApp @ +2349020812126 Email: scrollsgospel@gmail.com |